Oro nipa dundun ti o je ilu kan pataki ni ile Yoruba ni onkowe yii soro le lori. O menu ba ipo dundun ninu asa Yoruba, itan ti o je mo dundun, ibi ti a ti maa n lo o ti o si fi ibi aseye kan se apeere. O soro nipa bi won sen se e ati awon ilu miiran ti won maa n lu mo on. Aworan po ninu iwe naa. Ami ti awon onitilutifon maa n lo fun orin naa wa ninu re pelu.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
© MMXXIII Rich X Search. We shall prevail. All rights reserved. Rich X Search