Awujale

Awùjalẹ̀̀ ni orúkọ oyè Ọba ìbílẹ̀ Ìjẹ̀bú. Ẹni tó bá wà ní ipò yìí ni wọ́n ń pè ní Awùjalẹ̀ ti Ìjẹ̀bú.[1] Awùjalẹ̀ tó wà lórí oyè lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Ọba Sikiru Kayode Adetona Ògbágbá Kejì, tí ó wá láti ìdílé Anikinaiya.

Nínú ìwé òfin ti àwọn lọ́balọ́ba tó ń ṣàkóso ìlú Ìjẹ̀bú, àwọn ìdílé Ọlọ́ba mẹ́rin ni ó wà:[2]

  1. Ìdílé Gbelegbuwa
  2. Ìdílé Anikinaiya
  3. Ìdílé Fusengbuwa
  4. Ìdílé Moyegeso

Ọjọ́ kìíní oṣù kẹsàn-án ọdún 1959 ni wọ́n fi èyí lélẹ̀.

  1. "Ijebu History". ijebumn.org. Archived from the original on 27 January 2017. Retrieved 30 June 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Ijebu Community Association | History". Archived from the original on 13 March 2016. Retrieved 26 February 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)

© MMXXIII Rich X Search. We shall prevail. All rights reserved. Rich X Search